sentence stringlengths 21 391 |
|---|
Iléẹjọ́ ní kí Dáre gé oko àgọ́ ọlọ́pàá fọ́jọ́ méjì. |
Gbajúmọ̀ olukọ ni Fẹmi Ọlọ́runníṣọla lásìkò ogun jálumi |
Ọmọ kan káwọ́ sẹ́yìn rojọ́ lórí ẹ̀sùn láti gbẹ̀mí ìyá rẹ̀. |
Èyí ni àwọn ìpa tó yẹ kí ìjọba kọ́ lórí ìlọsíwájú àwọn ọ̀dọ́. |
Adéwálé Ẹlẹ́ṣọ̀ọ́ ní àìkàwé ló ṣàkóbá fún òun nínú iṣẹ́ tíátà. |
Mímikò ti padà sí ẹgbẹ́ rẹ̀ àtijọ́ lẹ́yìn ìpàdé ìdákọ́ńkọ́ |
Àjọ tó ń mójútó ètò ìdìbò nílẹ̀ yí ti ṣe àkójọpọ̀ orúkọ ọdún yìí |
Ẹ̀kọ́ márùn-ún tí wà láti dẹ́kun àjàkálẹ̀ ààrùn. |
Àwọn òṣìṣẹ́ padà sí ẹnu iṣẹ́ ní ìpińlẹ̀ Ọ̀ṣun. |
Àwọn obìnrin dáwó ra ọkọ̀ láti máa fi gbé aláboyún. |
Iṣẹ́ yíyàwòrán ti di iṣẹ́ tí gbogbo ọ̀dọ́ fẹ́ ṣe. |
Ìgbòho ké sáwọn olólùfẹ́ rẹ̀ láti dáríji agbẹjọ́rò rẹ̀. |
Obìnrin tó ló ìwé kíkọ́ láti tọ́ ara rẹ ti di olówó báyìí |
Ẹ̀sùn ìpànìyàn ti wọ́pọ̀ jù ní ìlú Ìbàdàn. |
Bọ̀dé sọ pé ẹ̀ẹ̀kan péré ni òun bá ẹgbẹ́ òṣèlú òun ṣeré papọ̀ |
Tinubu ṣe iṣẹ́ abẹ nílùú òyìnbó. |
Adé ṣàlàyé bó ṣe di agbẹjọ́rò fún Bàbá Ìjẹ̀sà. |
Wọ́n fárígá pé ẹ̀tàn ló fi ń ṣe ìjọba rẹ̀. |
Àṣírí ọ̀nà àbáyọ sí gbogbo ọ̀rọ̀ Nàìjíríà ni ká máa gbàdúrà. |
Èyí ni ètò ìsìnkú Aàrẹ ìlú Òkè Ọya kan tó kú lánàá |
Àjọ aṣóbodè ti kìlọ̀ fún àwọn ilé iṣẹ́ ìjọba láti dẹ́kun ríra ọkọ̀ tòkunbọ̀ |
Ó ní ọwọ́ àwọn ológun ló lè ká rògbòdìnyàn tó ń lọ lọ́wọ́. |
Àkànbí dèrò ọ̀run nítorí 'Eré orí ẹní' ní ìlú Èkó |
Àìgbọ́raẹniyé ló wáyé láàrín Bọ́lá ài igbákejì ẹ̀ lọ́jọ́ náà |
Ìjọba àpapọ̀ ní ẹjọ́ láti jẹ lórí ìpànìyàn náà. |
Adé gbàlejò akọ̀wé Amẹ́ríkà lánàá. |
Àdúrà ni orílẹ̀-èdè yìí nílò. |
Kò sí ẹni tó ní kí ń má wá sí Èkó. |
Wo àkọsílẹ̀ nípa ìtan ayé àwọn oludìbò gómìnà Ọ̀yọ́. |
Akọrin ẹ̀mí ní àánú Ọlọ́run ló sọ òun di akọrin. |
Ayé ni Adẹ́mọ́lá fẹ́ jẹ kí n tó sọ̀rọ̀ ọ̀run. |
Ẹnikẹ́ni tó bá gbélé fún ọmọ oníjìbìtì ma ṣẹ̀wọ̀n. |
Adébánjo ní àwọn ọ̀dọ́mọkùnrin gbọdọ̀ darapọ̀ mọ́ ìjọba. |
Mo bẹ Àdùnní kó bá mi se ọbẹ̀ tí màá fi jẹun. |
Ṣé òótọ ni pé ènìyàn leè kó ààrùn olóde láti ara bàtà? |
Agbẹjọ́rò ní kò sí àrídájú pé Ìgbòho ló ni ilé tí ìjọba kọlù. |
Ìró ìbọn yìí dún gbàù lásìkò ìpàdé àwọ ọmọlẹ́yìn Arẹ́gbẹ́ṣọlá |
Ọlọ́pàá ní àwọn ti mú afunrasí kan tó mọ̀ nípa ikú Bísọ́lá |
Àgùnbánirọ̀ sọ pé omi àti iyẹ̀pẹ̀ ni sọ́jà fi bá òun jà |
Èdè aìyedè wà lórí bí ẹ̀gbọ́n ìyàwó Bukola ṣe kú ní Èkó. |
Ìlànà Ọmọ Yorùbá ṣe pàtàkì fún wa. |
Mo nífẹ̀ẹ́ sí kin máa mu Gàrí ní Nàìjíríà ju ìlú mi lọ. |
Adé jáde láyé lẹ́ni ọmọ ogún ọdún. |
Àrùn ọpọlọ ń da ọ̀pọ̀lọpọ̀ èèyàn láàmú ní ilé Adébọ̀wálé |
Owó púpọ̀ ni màmá náà nílò láti ṣòwò jèrè lọ́jà. |
Ọ̀pọ àwọn akékọ̀ọ́ ti wá nnkan mìíràn ṣe nínú ìyanṣélódì. |
Àwọn ọlọ́pàá ìpínlẹ̀ Òǹdó ṣì ń tẹ̀síwájú nínú ìwádìí wọn. |
Ibi tí àwọn nọ́ọ̀sí ti ń ṣiṣẹ́ kò pójú òṣùwọ̀n rárá. |
Àjọ tó ń rísí ìtọ́jú àwọn ará ìlú ti kéde ènìyàn méji tó kú. |
Ìyàwó mi fi mí sílẹ̀ kó lọ sílé ọkùnrin míì nínú báráàkì kan náà. |
Àwọn akẹ́kọ̀ọ́ mẹ́rìnlà ló pàdánù ẹ̀mí wọn nínú ìjàm̀bá |
Oluwapọ̀nmile sọ ìrírí rẹ̀ lọ́wọ́ àwọn sójà tó fìyàjẹ́ ní Ibadan. |
Ọmọ náà ló máa n fa àwọn ìjà kéékèèké láàárín ìyá àti bàbá rẹ̀ |
Ohun méta rèé tó máa ń fa kí orí máa fọ́ ènìyàn |
Gómìnà Akérédolú la Jégédé mọ́lẹ̀ wọlé ìbò gómìnà Òǹdó. |
Àbáyọ̀mí ti rọ àwọn ọ̀dọ́ láti ṣọ́ra, ki wọ́n má baà di ẹran àmúso |
Ààrẹ ìlú kan ní Áfíríkà ṣ'èdárò Ẹja akóredé tó papòdà. |
Arẹ́gbẹ́ṣọlá sọ pé àwọn ẹlẹ́sìn ìbílẹ̀ ló máà ń mu ọtí jù |
Ọmọ títọ́ kìí ṣe tí àwọn òbí nìkan, gbogbo àwùjọ ló ń tọ ọmọ. |
Iléeṣẹ ọlọpàá mú Adé lorí pé o fipá bá akẹkọọ lò pọ. |
Ìran Yorùbá kìí ṣe ọ̀lẹ tàbí olè rárá. |
Mo gbàdúrà kí Ọlọ́run tu gbogbo ẹbí wa nínú. |
Dáramọ́la Abíọ́dún tó jé agbenusọ fún ìjọba ló ṣẹ̀ṣẹ̀ dé |
Ìgbìmọ̀ aṣòfin ní àwọn kò tíì gbọ́ nípa ikú aṣòfin ìpínlẹ̀ Eko to kú |
Ta ló tún fé bá mi ní ìbálòpọ̀ọ̀ báyìí? |
Àwọn jàǹdùkú kan ti ń dúnkookò mọ ọrọ̀ ajé àwọn ọlọ́jà. |
Ìdìtẹ̀gbàjọba gbàjọba ti ṣẹlẹ̀ láìmọye ìgbà nílè Nàíjíríà. |
Ọba Gbọ́láhàn Shómólú ti jẹ́wọ́ pé àṣìṣe ni òun ṣe. |
Ọ̀pọ̀ ọ̀gá òṣèré ló ń bèèrè ìbálòpọ̀ lọ́wọ́ àwọn ègbè lẹ́yìn wọn |
Àwọn òṣìṣẹ́ kólẹ̀-kódọ̀tí ń fi ẹ̀mí wọn wéwu ní ìlú Èkó. |
Agbẹjọ́rò Báyọ̀ ní ìbanilórúkọjẹ́ ní wọ́n fí ẹ̀sùn gbájúẹ̀ ṣe. |
Ìpolongo ìdíje sípò gómínà ti gbéraṣo ní ìlú Ọ̀ṣun. |
Ọ̀gá ọlọ́pàá pàṣẹ pé kí wọ́n ṣé ìwádìí lórí ọlọ́pàá inú àwòrán. |
Àwọn aláṣẹ kejì yìí ló ṣàlàyé bí ìbọn ṣe bá akẹ́kọ̀ọ́ àkọ́kọ́ |
Gómìnà ìlú Èkìtì fi ipò kejì dá Sànúsí lọlá láàárín ọjọ́ méjì. |
Adépọ̀jù ti dé iwájú adájọ́ méjì kó tó rí àánú gbà |
Simi àti ọkọ ẹ̀ ti darí sí ìlú òyìnbó láti pàdé àwọn ẹbí wọn |
Ẹ wo báwọn ọmọ ọ̀ṣọtà ṣe ya bó màmá Ire. |
Akérédelú ní Bọ́lá kájúẹ̀ láti ṣe àkóso Nàíjíríà. |
Títí di ìparí oṣù kẹwàá ni a ó gba ìwé-àṣẹ ìwakọ̀ |
Dókítà Àlàní ti kó àrùn tí kò gbọ́ òògùn. |
N kò gba kọ́bọ̀ lọ́wọ́ ẹnikẹ́ni láti wá náà ọ̀daràn jáde. |
Àǹfààní márùn-ún ló wá nínú ìmọ̀ nípa ìṣòwò lọ́ja Ayẹ́yẹ́ |
Wọ́n yìbọn sókè káàkiri nínú agbègbè Gbági, mo sì sá lọ. |
Owó oúnjẹ ni mo lọ ọ gbà lọ́wọ́ bàbá mi. |
Yorùbá béèrè kókó ǹkan mẹ́fà lọ́wọ́ Adẹ́mọ́lá. |
Ẹniọlá Adékúnlé ti gbé fọ́tò bàbá ẹ̀ sálọ sínú igbó |
Mo gbọ pé ilé ìgbìmọ̀ aṣòfin júwe ilé fáwọn alága ìjọba ìbílẹ̀ |
Yínká fún Ìkẹ́olúwa ní oyún lẹ́yìn ọdún méjì tí wón ti wà. |
Àwọn ọlọ́pàá kan ti pàdé Babájídé láti bèère oun tí wọ́n fẹ́ |
Olóyè Ayọ̀ ti ń bèèrè ìtúsílẹ̀ àwọn tí wọ́n jí gbé báyìí |
Àwọn akẹ́kọ̀ọ́ ti fòpin sí ìyanṣẹ́lódì ọlọ́jọ́ mẹ́rin wọn |
Kúnlé fẹ́ràn iyan àti ẹran ìgbẹ́. |
Màmá Sọjí ti di asojú ilé iṣẹ́ kan nílẹ̀ òkèrè. |
Ilé ẹjọ́ dá arákùnrin náà dúró láti gbé ọmọ ógún ọdún sílé. |
Ọmọ ilé ẹ̀kọ́ wa méjì fórí kó ọta ìbọn lọ́jọ́ kan ṣoṣo. |
Ojú àwọn ará Èkó rí màbo pẹ̀lú òjò àrọ̀ọ̀rọ̀dá tó bẹ́ sílẹ̀. |
Ọbásanjọ́ ti kọ̀ nítorí wàhálà tó ń wáyé lẹ́gbẹ́ òṣèlú rẹ̀ |
Èmi kọ́ ló gbé orin ọdún ń lọ sópin kalẹ̀. |
Kokoko lara mí le, Mo kàn ń gbà ìtọ́jú nílé ìwòsàn ni |
Subsets and Splits
No community queries yet
The top public SQL queries from the community will appear here once available.